Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 5 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿أُوْلَٰٓئِكَ عَلَىٰ هُدٗى مِّن رَّبِّهِمۡۖ وَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡمُفۡلِحُونَ ﴾
[البَقَرَة: 5]
﴿أولئك على هدى من ربهم وأولئك هم المفلحون﴾ [البَقَرَة: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn wà lórí ìmọ̀nà láti ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. Àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni olùjèrè |