Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 105 - طه - Page - Juz 16
﴿وَيَسۡـَٔلُونَكَ عَنِ ٱلۡجِبَالِ فَقُلۡ يَنسِفُهَا رَبِّي نَسۡفٗا ﴾
[طه: 105]
﴿ويسألونك عن الجبال فقل ينسفها ربي نسفا﴾ [طه: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń bi ọ́ léèrè nípa àwọn àpáta. Sọ pé: “Olúwa mi yóò kù wọ́n dànù tán ráúráú |