Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 2 - طه - Page - Juz 16
﴿مَآ أَنزَلۡنَا عَلَيۡكَ ٱلۡقُرۡءَانَ لِتَشۡقَىٰٓ ﴾
[طه: 2]
﴿ما أنـزلنا عليك القرآن لتشقى﴾ [طه: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ fún ọ láti kó wàhálà bá ọ |