Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 4 - طه - Page - Juz 16
﴿تَنزِيلٗا مِّمَّنۡ خَلَقَ ٱلۡأَرۡضَ وَٱلسَّمَٰوَٰتِ ٱلۡعُلَى ﴾
[طه: 4]
﴿تنـزيلا ممن خلق الأرض والسموات العلا﴾ [طه: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó jẹ́) ìmísí t’ó sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Ẹni tí Ó dá ilẹ̀ àti àwọn sánmọ̀ gíga |