Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 42 - طه - Page - Juz 16
﴿ٱذۡهَبۡ أَنتَ وَأَخُوكَ بِـَٔايَٰتِي وَلَا تَنِيَا فِي ذِكۡرِي ﴾
[طه: 42]
﴿اذهب أنت وأخوك بآياتي ولا تنيا في ذكري﴾ [طه: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lọ, ìwọ àti arákùnrin rẹ, pẹ̀lú àwọn àmì (iṣẹ́ ìyanu) Mi. Kí ẹ sì má ṣe kọ́lẹ nínú ìrántí Mi |