Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 85 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَإِسۡمَٰعِيلَ وَإِدۡرِيسَ وَذَا ٱلۡكِفۡلِۖ كُلّٞ مِّنَ ٱلصَّٰبِرِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 85]
﴿وإسماعيل وإدريس وذا الكفل كل من الصابرين﴾ [الأنبيَاء: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹ rántí Ànábì) ’Ismọ̄‘īl àti (Ànábì) ’Idrīs àti (Ànábì) Thul-Kifl; ẹnì kọ̀ọ̀kan (wọn) wà nínú àwọn onísùúrù |