Quran with Yoruba translation - Surah An-Nur ayat 44 - النور - Page - Juz 18
﴿يُقَلِّبُ ٱللَّهُ ٱلَّيۡلَ وَٱلنَّهَارَۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَعِبۡرَةٗ لِّأُوْلِي ٱلۡأَبۡصَٰرِ ﴾
[النور: 44]
﴿يقلب الله الليل والنهار إن في ذلك لعبرة لأولي الأبصار﴾ [النور: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu ń mú òru àti ọ̀sán tẹ̀lé ara wọn ní tẹ̀léǹtẹ̀lé. Dájúdájú àríwòye wà nínú ìyẹn fún àwọn t’ó ní ojú ìríran |