Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 6 - الفُرقَان - Page - Juz 18
﴿قُلۡ أَنزَلَهُ ٱلَّذِي يَعۡلَمُ ٱلسِّرَّ فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ إِنَّهُۥ كَانَ غَفُورٗا رَّحِيمٗا ﴾
[الفُرقَان: 6]
﴿قل أنـزله الذي يعلم السر في السموات والأرض إنه كان غفورا رحيما﴾ [الفُرقَان: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Ẹni tí Ó mọ ìkọ̀kọ̀ tí ń bẹ nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ l’Ó sọ̀ ọ́ kalẹ̀. Dájúdájú Òun ni Ó ń jẹ́ Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run |