Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 38 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَجُمِعَ ٱلسَّحَرَةُ لِمِيقَٰتِ يَوۡمٖ مَّعۡلُومٖ ﴾
[الشعراء: 38]
﴿فجمع السحرة لميقات يوم معلوم﴾ [الشعراء: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì kó àwọn òpìdán jọ ní àsìkò tí wọ́n fi àdéhùn sí ní ọjọ́ tí (gbogbo ìlú) ti mọ̀ |