Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 70 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِذۡ قَالَ لِأَبِيهِ وَقَوۡمِهِۦ مَا تَعۡبُدُونَ ﴾
[الشعراء: 70]
﴿إذ قال لأبيه وقومه ما تعبدون﴾ [الشعراء: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí ó sọ fún bàbá rẹ̀ àti àwọn ènìyàn rẹ̀ pé: “Kí ni n̄ǹkan tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún ná?” |