Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 86 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَٱغۡفِرۡ لِأَبِيٓ إِنَّهُۥ كَانَ مِنَ ٱلضَّآلِّينَ ﴾
[الشعراء: 86]
﴿واغفر لأبي إنه كان من الضالين﴾ [الشعراء: 86]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí O sì foríjin bàbá mi. Dájúdájú ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn olùṣìnà |