Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 54 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿وَلُوطًا إِذۡ قَالَ لِقَوۡمِهِۦٓ أَتَأۡتُونَ ٱلۡفَٰحِشَةَ وَأَنتُمۡ تُبۡصِرُونَ ﴾
[النَّمل: 54]
﴿ولوطا إذ قال لقومه أتأتون الفاحشة وأنتم تبصرون﴾ [النَّمل: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A tún fi iṣẹ́ ìmísí rán Ànábì) Lūt. (Rántí) nígbà tí ó sọ fún ìjọ rẹ̀ pé: "Ṣé iṣẹ́ aburú ni ẹ óò máa ṣe ni, ẹ sì ríran |