Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 58 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿وَأَمۡطَرۡنَا عَلَيۡهِم مَّطَرٗاۖ فَسَآءَ مَطَرُ ٱلۡمُنذَرِينَ ﴾
[النَّمل: 58]
﴿وأمطرنا عليهم مطرا فساء مطر المنذرين﴾ [النَّمل: 58]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A rọ òjò lé wọn lórí tààrà. Òjò àwọn tí A kìlọ̀ fún sì burú |