Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 89 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿مَن جَآءَ بِٱلۡحَسَنَةِ فَلَهُۥ خَيۡرٞ مِّنۡهَا وَهُم مِّن فَزَعٖ يَوۡمَئِذٍ ءَامِنُونَ ﴾
[النَّمل: 89]
﴿من جاء بالحسنة فله خير منها وهم من فزع يومئذ آمنون﴾ [النَّمل: 89]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú iṣẹ́ rere wá, tirẹ̀ ni rere t’ó lóore jùlọ sí èyí t’ó mú wá. Àwọn sì ni olùfàyàbalẹ̀ nínú ìjáyà ọjọ́ yẹn |