Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 65 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿وَيَوۡمَ يُنَادِيهِمۡ فَيَقُولُ مَاذَآ أَجَبۡتُمُ ٱلۡمُرۡسَلِينَ ﴾
[القَصَص: 65]
﴿ويوم يناديهم فيقول ماذا أجبتم المرسلين﴾ [القَصَص: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) ọjọ́ tí (Allāhu) yóò pè wọ́n, Ó sì máa sọ pé: “Kí ni ẹ fọ̀ ní èsì fún àwọn Òjíṣẹ́?” |