Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 98 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿قُلۡ يَٰٓأَهۡلَ ٱلۡكِتَٰبِ لِمَ تَكۡفُرُونَ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ وَٱللَّهُ شَهِيدٌ عَلَىٰ مَا تَعۡمَلُونَ ﴾ 
[آل عِمران: 98]
﴿قل ياأهل الكتاب لم تكفرون بآيات الله والله شهيد على ما تعملون﴾ [آل عِمران: 98]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Ẹ̀yin ahlul-kitāb, nítorí kí ni ẹ óò fi ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Allāhu? Allāhu sì ni Arínú-róde ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́  |