Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 35 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿أَمۡ أَنزَلۡنَا عَلَيۡهِمۡ سُلۡطَٰنٗا فَهُوَ يَتَكَلَّمُ بِمَا كَانُواْ بِهِۦ يُشۡرِكُونَ ﴾
[الرُّوم: 35]
﴿أم أنـزلنا عليهم سلطانا فهو يتكلم بما كانوا به يشركون﴾ [الرُّوم: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí A sọ ẹ̀rí kan kalẹ̀ fún wọn, t’ó ń sọ̀rọ̀ nípa n̄ǹkan tí wọ́n ń sọ di akẹgbẹ́ Rẹ̀ |