Quran with Yoruba translation - Surah Luqman ayat 5 - لُقمَان - Page - Juz 21
﴿أُوْلَٰٓئِكَ عَلَىٰ هُدٗى مِّن رَّبِّهِمۡۖ وَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡمُفۡلِحُونَ ﴾
[لُقمَان: 5]
﴿أولئك على هدى من ربهم وأولئك هم المفلحون﴾ [لُقمَان: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn wà lórí ìmọ̀nà láti ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. Àwọn wọ̀nyẹn sì ni àwọn olùjèrè |