Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 49 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿قُلۡ جَآءَ ٱلۡحَقُّ وَمَا يُبۡدِئُ ٱلۡبَٰطِلُ وَمَا يُعِيدُ ﴾
[سَبإ: 49]
﴿قل جاء الحق وما يبدئ الباطل وما يعيد﴾ [سَبإ: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Òdodo ti dé. Irọ́ (èṣù) kò lè mú n̄ǹkan bẹ, kò sì lè dá n̄ǹkan padà (lẹ́yìn tó ti kú).” |