Quran with Yoruba translation - Surah FaTir ayat 30 - فَاطِر - Page - Juz 22
﴿لِيُوَفِّيَهُمۡ أُجُورَهُمۡ وَيَزِيدَهُم مِّن فَضۡلِهِۦٓۚ إِنَّهُۥ غَفُورٞ شَكُورٞ ﴾
[فَاطِر: 30]
﴿ليوفيهم أجورهم ويزيدهم من فضله إنه غفور شكور﴾ [فَاطِر: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọ́n ń ṣe bẹ́ẹ̀) nítorí kí Allāhu lè san wọ́n ní ẹ̀san rere wọn àti nítorí kí Ó lè ṣe àlékún fún wọn nínú oore àjùlọ Rẹ̀. Dájúdájú Òun ni Aláforíjìn, Ọlọ́pẹ́ |