Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 126 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿ٱللَّهَ رَبَّكُمۡ وَرَبَّ ءَابَآئِكُمُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[الصَّافَات: 126]
﴿الله ربكم ورب آبائكم الأولين﴾ [الصَّافَات: 126]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (ẹ̀ ń fi) Allāhu (sílẹ̀), Olúwa yín àti Olúwa àwọn bàbá yín, àwọn ẹni àkọ́kọ́ |