Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 49 - صٓ - Page - Juz 23
﴿هَٰذَا ذِكۡرٞۚ وَإِنَّ لِلۡمُتَّقِينَ لَحُسۡنَ مَـَٔابٖ ﴾
[صٓ: 49]
﴿هذا ذكر وإن للمتقين لحسن مآب﴾ [صٓ: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí ni ìrántí. Àti pé dájúdájú àbọ̀ rere wà fún àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) |