Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 66 - صٓ - Page - Juz 23
﴿رَبُّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَمَا بَيۡنَهُمَا ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡغَفَّٰرُ ﴾
[صٓ: 66]
﴿رب السموات والأرض وما بينهما العزيز الغفار﴾ [صٓ: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti ohunkóhun t’ó wà láààrin méjèèjì, Alágbára, Aláforíjìn |