Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 65 - صٓ - Page - Juz 23
﴿قُلۡ إِنَّمَآ أَنَا۠ مُنذِرٞۖ وَمَا مِنۡ إِلَٰهٍ إِلَّا ٱللَّهُ ٱلۡوَٰحِدُ ٱلۡقَهَّارُ ﴾
[صٓ: 65]
﴿قل إنما أنا منذر وما من إله إلا الله الواحد القهار﴾ [صٓ: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Èmi ni olùkìlọ̀. Àti pé kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àyàfi Allāhu, Ọ̀kan ṣoṣo, Olùborí |