Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 9 - صٓ - Page - Juz 23
﴿أَمۡ عِندَهُمۡ خَزَآئِنُ رَحۡمَةِ رَبِّكَ ٱلۡعَزِيزِ ٱلۡوَهَّابِ ﴾
[صٓ: 9]
﴿أم عندهم خزائن رحمة ربك العزيز الوهاب﴾ [صٓ: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí (ṣé) àwọn ni wọ́n ni àwọn àpótí ọ̀rọ̀ Olúwa rẹ, Alágbára, Ọlọ́rẹ |