×

Awon wonyen ni awon ti Allahu mo ohun ti n be ninu 4:63 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:63) ayat 63 in Yoruba

4:63 Surah An-Nisa’ ayat 63 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 63 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿أُوْلَٰٓئِكَ ٱلَّذِينَ يَعۡلَمُ ٱللَّهُ مَا فِي قُلُوبِهِمۡ فَأَعۡرِضۡ عَنۡهُمۡ وَعِظۡهُمۡ وَقُل لَّهُمۡ فِيٓ أَنفُسِهِمۡ قَوۡلَۢا بَلِيغٗا ﴾
[النِّسَاء: 63]

Awon wonyen ni awon ti Allahu mo ohun ti n be ninu okan won. Nitori naa, seri kuro lodo won. Se waasi fun won, ki o si ba won so oro t’o lagbara nipa ara won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: أولئك الذين يعلم الله ما في قلوبهم فأعرض عنهم وعظهم وقل لهم, باللغة اليوربا

﴿أولئك الذين يعلم الله ما في قلوبهم فأعرض عنهم وعظهم وقل لهم﴾ [النِّسَاء: 63]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn tí Allāhu mọ ohun tí ń bẹ nínú ọkàn wọn. Nítorí náà, ṣẹ́rí kúrò lọ́dọ̀ wọn. Ṣe wáàsí fún wọn, kí o sì bá wọn sọ ọ̀rọ̀ t’ó lágbára nípa ara wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek