×

Bawo ni o se je pe nigba ti adanwo kan ba kan 4:62 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:62) ayat 62 in Yoruba

4:62 Surah An-Nisa’ ayat 62 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 62 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿فَكَيۡفَ إِذَآ أَصَٰبَتۡهُم مُّصِيبَةُۢ بِمَا قَدَّمَتۡ أَيۡدِيهِمۡ ثُمَّ جَآءُوكَ يَحۡلِفُونَ بِٱللَّهِ إِنۡ أَرَدۡنَآ إِلَّآ إِحۡسَٰنٗا وَتَوۡفِيقًا ﴾
[النِّسَاء: 62]

Bawo ni o se je pe nigba ti adanwo kan ba kan won nipase ohun ti owo won ti siwaju, leyin naa won maa wa ba o, won yo si maa fi Allahu bura pe ko si ohun ti a gba lero bi ko se daadaa ati irepo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فكيف إذا أصابتهم مصيبة بما قدمت أيديهم ثم جاءوك يحلفون بالله إن, باللغة اليوربا

﴿فكيف إذا أصابتهم مصيبة بما قدمت أيديهم ثم جاءوك يحلفون بالله إن﴾ [النِّسَاء: 62]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Báwo ni ó ṣe jẹ́ pé nígbà tí àdánwò kan bá kàn wọ́n nípasẹ̀ ohun tí ọwọ́ wọ́n tì síwájú, lẹ́yìn náà wọ́n máa wá bá ọ, wọ́n yó sì máa fi Allāhu búra pé kò sí ohun tí a gbà lérò bí kò ṣe dáadáa àti ìrẹ́pọ̀
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek