×

A o ran Ojise kan nise afi nitori ki won le tele 4:64 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:64) ayat 64 in Yoruba

4:64 Surah An-Nisa’ ayat 64 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 64 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿وَمَآ أَرۡسَلۡنَا مِن رَّسُولٍ إِلَّا لِيُطَاعَ بِإِذۡنِ ٱللَّهِۚ وَلَوۡ أَنَّهُمۡ إِذ ظَّلَمُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ جَآءُوكَ فَٱسۡتَغۡفَرُواْ ٱللَّهَ وَٱسۡتَغۡفَرَ لَهُمُ ٱلرَّسُولُ لَوَجَدُواْ ٱللَّهَ تَوَّابٗا رَّحِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 64]

A o ran Ojise kan nise afi nitori ki won le tele e pelu iyonda Allahu. Ti o ba je pe nigba ti won sabosi si emi ara won, won wa ba o, won si toro aforijin Allahu, ti Ojise si tun ba won toro aforijin, won iba kuku ri Allahu ni Olugba-ironupiwada, Asake-orun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما أرسلنا من رسول إلا ليطاع بإذن الله ولو أنهم إذ ظلموا, باللغة اليوربا

﴿وما أرسلنا من رسول إلا ليطاع بإذن الله ولو أنهم إذ ظلموا﴾ [النِّسَاء: 64]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
A ò rán Òjíṣẹ́ kan níṣẹ́ àfi nítorí kí wọ́n lè tẹ̀lé e pẹ̀lú ìyọ̀ǹda Allāhu. Tí ó bá jẹ́ pé nígbà tí wọ́n ṣàbòsí sí ẹ̀mí ara wọn, wọ́n wá bá ọ, wọ́n sì tọrọ àforíjìn Allāhu, tí Òjíṣẹ́ sì tún bá wọn tọrọ àforíjìn, wọn ìbá kúkú rí Allāhu ní Olùgba-ìronúpìwàdà, Àṣàkẹ́-ọ̀run
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek