Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 32 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿وَمِنۡ ءَايَٰتِهِ ٱلۡجَوَارِ فِي ٱلۡبَحۡرِ كَٱلۡأَعۡلَٰمِ ﴾
[الشُّوري: 32]
﴿ومن آياته الجوار في البحر كالأعلام﴾ [الشُّوري: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún wà nínú àwọn àmì Rẹ̀, àwọn ọkọ̀ ojú-omi t’ó ń rìn lójú omi (t’ó dà) bí àwọn òkè àpáta gíga |