Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 4 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿لَهُۥ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَمَا فِي ٱلۡأَرۡضِۖ وَهُوَ ٱلۡعَلِيُّ ٱلۡعَظِيمُ ﴾
[الشُّوري: 4]
﴿له ما في السموات وما في الأرض وهو العلي العظيم﴾ [الشُّوري: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni TiRẹ̀ ni ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ohunkóhun t’ó wà nínú ilẹ̀. Ó ga, Ó tóbi |