Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 79 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿أَمۡ أَبۡرَمُوٓاْ أَمۡرٗا فَإِنَّا مُبۡرِمُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 79]
﴿أم أبرموا أمرا فإنا مبرمون﴾ [الزُّخرُف: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí àwọn (aláìgbàgbọ́) ti pinnu ọ̀rọ̀ kan ni? Dájúdájú Àwa náà ń pinnu ọ̀rọ̀ |