Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 38 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿وَمَا خَلَقۡنَا ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَ وَمَا بَيۡنَهُمَا لَٰعِبِينَ ﴾
[الدُّخان: 38]
﴿وما خلقنا السموات والأرض وما بينهما لاعبين﴾ [الدُّخان: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀, ilẹ̀ àti ohunkóhun tí ń bẹ láààrin méjèèjì pẹ̀lú eré ṣíṣe |