Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 39 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿مَا خَلَقۡنَٰهُمَآ إِلَّا بِٱلۡحَقِّ وَلَٰكِنَّ أَكۡثَرَهُمۡ لَا يَعۡلَمُونَ ﴾
[الدُّخان: 39]
﴿ما خلقناهما إلا بالحق ولكن أكثرهم لا يعلمون﴾ [الدُّخان: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò dá àwọn méjèèjì bí kò ṣe pẹ̀lú òdodo, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò mọ̀ |