Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 6 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿رَحۡمَةٗ مِّن رَّبِّكَۚ إِنَّهُۥ هُوَ ٱلسَّمِيعُ ٱلۡعَلِيمُ ﴾
[الدُّخان: 6]
﴿رحمة من ربك إنه هو السميع العليم﴾ [الدُّخان: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìkẹ́ kan ni láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ. Dájúdájú Allāhu, Òun ni Olùgbọ́, Onímọ̀ |