Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 5 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿سَيَهۡدِيهِمۡ وَيُصۡلِحُ بَالَهُمۡ ﴾
[مُحمد: 5]
﴿سيهديهم ويصلح بالهم﴾ [مُحمد: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó máa tọ́ wọn sọ́nà. Ó sì máa tún ọ̀rọ̀ wọn ṣe sí dáadáa |