Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 15 - الفَتح - Page - Juz 26
﴿سَيَقُولُ ٱلۡمُخَلَّفُونَ إِذَا ٱنطَلَقۡتُمۡ إِلَىٰ مَغَانِمَ لِتَأۡخُذُوهَا ذَرُونَا نَتَّبِعۡكُمۡۖ يُرِيدُونَ أَن يُبَدِّلُواْ كَلَٰمَ ٱللَّهِۚ قُل لَّن تَتَّبِعُونَا كَذَٰلِكُمۡ قَالَ ٱللَّهُ مِن قَبۡلُۖ فَسَيَقُولُونَ بَلۡ تَحۡسُدُونَنَاۚ بَلۡ كَانُواْ لَا يَفۡقَهُونَ إِلَّا قَلِيلٗا ﴾
[الفَتح: 15]
﴿سيقول المخلفون إذا انطلقتم إلى مغانم لتأخذوها ذرونا نتبعكم يريدون أن يبدلوا﴾ [الفَتح: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn olùsásẹ́yìn fún ogun (Hudaebiyyah) ń wí pé: "Nígbà tí ẹ lọ síbi ọrọ̀-ogun (Kaebar) nítorí kí ẹ lè rí n̄ǹkan kó, wọ́n já wa jù sílẹ̀ kí á má lè tẹ̀lé yín lọ." (Àwọn olùsásẹ́yìn wọ̀nyí) sì ń gbèrò láti yí ọ̀rọ̀ Allāhu padà ni. (Ìwọ Ànábì) sọ pé: "Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ tẹ̀lé wa. Báyẹn ni Allāhu ṣe sọ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀." Wọn yó sì tún wí pé: "Rárá (kò rí bẹ́ẹ̀), ẹ̀ ń ṣe kèéta wa ni." Rárá (ẹ̀yin kò ṣe kèéta wọn, àmọ́), wọ́n kì í gbọ́ àgbọ́yé (ọ̀rọ̀) àfi díẹ̀ |