Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 74 - المَائدة - Page - Juz 6
﴿أَفَلَا يَتُوبُونَ إِلَى ٱللَّهِ وَيَسۡتَغۡفِرُونَهُۥۚ وَٱللَّهُ غَفُورٞ رَّحِيمٞ ﴾
[المَائدة: 74]
﴿أفلا يتوبون إلى الله ويستغفرونه والله غفور رحيم﴾ [المَائدة: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣé wọn kò níí ronú pìwàdà sọ́dọ̀ Allāhu, kí wọ́n sì tọrọ àforíjìn lọ́dọ̀ Rẹ̀? Allāhu sì ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run |