Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 88 - المَائدة - Page - Juz 7
﴿وَكُلُواْ مِمَّا رَزَقَكُمُ ٱللَّهُ حَلَٰلٗا طَيِّبٗاۚ وَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ ٱلَّذِيٓ أَنتُم بِهِۦ مُؤۡمِنُونَ ﴾
[المَائدة: 88]
﴿وكلوا مما رزقكم الله حلالا طيبا واتقوا الله الذي أنتم به مؤمنون﴾ [المَائدة: 88]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ jẹ n̄ǹkan ẹ̀tọ́ t’ó dára nínú ohun tí Allāhu ṣe ní arísìkí fun yín. Àti pé ẹ bẹ̀rù Allāhu, Ẹni tí ẹ̀yin gbàgbọ́ nínú Rẹ̀ |