Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 26 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿فَرَاغَ إِلَىٰٓ أَهۡلِهِۦ فَجَآءَ بِعِجۡلٖ سَمِينٖ ﴾
[الذَّاريَات: 26]
﴿فراغ إلى أهله فجاء بعجل سمين﴾ [الذَّاريَات: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ará ilé rẹ̀, ó sì dé pẹ̀lú ọmọ màálù ọlọ́ràá (àyangbẹ) |