Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 55 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَذَكِّرۡ فَإِنَّ ٱلذِّكۡرَىٰ تَنفَعُ ٱلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الذَّاريَات: 55]
﴿وذكر فإن الذكرى تنفع المؤمنين﴾ [الذَّاريَات: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣèrántí nítorí pé, dájúdájú ìrántí máa wúlò fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo |