Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 56 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَمَا خَلَقۡتُ ٱلۡجِنَّ وَٱلۡإِنسَ إِلَّا لِيَعۡبُدُونِ ﴾
[الذَّاريَات: 56]
﴿وما خلقت الجن والإنس إلا ليعبدون﴾ [الذَّاريَات: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé Èmi kò ṣẹ̀dá àlùjànnú àti ènìyàn bí kò ṣe pé kí wọ́n lè jọ́sìn fún Mi |