Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 9 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿يُؤۡفَكُ عَنۡهُ مَنۡ أُفِكَ ﴾
[الذَّاريَات: 9]
﴿يؤفك عنه من أفك﴾ [الذَّاريَات: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí wọ́n ń ṣẹ́ lórí kúrò níbi al-Ƙur’ān ni ẹni tí Wọ́n ti ṣẹ́ lórí kúrò níbẹ̀ (láti inú Laohul-Mahfūṭḥ) |