Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 10 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿فَدَعَا رَبَّهُۥٓ أَنِّي مَغۡلُوبٞ فَٱنتَصِرۡ ﴾
[القَمَر: 10]
﴿فدعا ربه أني مغلوب فانتصر﴾ [القَمَر: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ó pe Olúwa rẹ̀ pé: "Dájúdájú wọ́n ti borí mi. Ràn mí lọ́wọ́ |