Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 11 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿فَفَتَحۡنَآ أَبۡوَٰبَ ٱلسَّمَآءِ بِمَآءٖ مُّنۡهَمِرٖ ﴾
[القَمَر: 11]
﴿ففتحنا أبواب السماء بماء منهمر﴾ [القَمَر: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A ṣí àwọn ìlẹ̀kùn sánmọ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú omi t’ó lágbára |