Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 36 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿وَلَقَدۡ أَنذَرَهُم بَطۡشَتَنَا فَتَمَارَوۡاْ بِٱلنُّذُرِ ﴾
[القَمَر: 36]
﴿ولقد أنذرهم بطشتنا فتماروا بالنذر﴾ [القَمَر: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó kúkú fi ìgbámú Wa ṣe ìkìlọ̀ fún wọn, ṣùgbọ́n wọ́n ja àwọn ìkìlọ̀ níyàn |