Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 35 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿نِّعۡمَةٗ مِّنۡ عِندِنَاۚ كَذَٰلِكَ نَجۡزِي مَن شَكَرَ ﴾
[القَمَر: 35]
﴿نعمة من عندنا كذلك نجزي من شكر﴾ [القَمَر: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó jẹ́) ìkẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Wa. Báyẹn ni A ṣe ń san ẹ̀san fún ẹni t’ó bá dúpẹ́ (fún Wa) |