Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 46 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿بَلِ ٱلسَّاعَةُ مَوۡعِدُهُمۡ وَٱلسَّاعَةُ أَدۡهَىٰ وَأَمَرُّ ﴾
[القَمَر: 46]
﴿بل الساعة موعدهم والساعة أدهى وأمر﴾ [القَمَر: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àmọ́ sá, Àkókò náà ni ọjọ́ àdéhùn wọn. Àkókò náà burú jùlọ. Ó sì korò jùlọ |