Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 24 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿وَلَهُ ٱلۡجَوَارِ ٱلۡمُنشَـَٔاتُ فِي ٱلۡبَحۡرِ كَٱلۡأَعۡلَٰمِ ﴾
[الرَّحمٰن: 24]
﴿وله الجوار المنشآت في البحر كالأعلام﴾ [الرَّحمٰن: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ti (Allāhu) ni àwọn ọkọ̀ ojú-omi gogoro t’ó ń rìn nínú agbami òdò (tí wọ́n dà) bí àpáta gíga |