Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 17 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿يَطُوفُ عَلَيۡهِمۡ وِلۡدَٰنٞ مُّخَلَّدُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 17]
﴿يطوف عليهم ولدان مخلدون﴾ [الوَاقِعة: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ọ̀dọ́kùnrin tí kò níí darúgbó yó sì máa lọ bọ̀ láààrin wọn |