Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 70 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿لَوۡ نَشَآءُ جَعَلۡنَٰهُ أُجَاجٗا فَلَوۡلَا تَشۡكُرُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 70]
﴿لو نشاء جعلناه أجاجا فلولا تشكرون﴾ [الوَاقِعة: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí A bá fẹ́ ni, Àwa ìbá ṣe é ní omi t’ó móró. Ẹ ò ṣe máa dúpẹ́ |